Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 1 nínú 14

Olorun nsoro ni ono pupo

Ni ese bibeli fun oni, Olorun fiwon pe Oun nsoro, ti Oun ba soro, Oun soro ni ododo. Nigbagbogbo lale ma farale ohun ti Olorun baso wipe otun ni. Olorun nbawa soro ni ona pupo to pelu laidopin si: Oro Re, Iseda, awon eyan, ayidayida, alafia, ọgbọn, idasi atonruwa, ala, iran' ati nnkan tiwon peni "ẹri atinuwa" ti ale peni "mimo" ninu okan wa. Otun nsoro gegebi oun ti Bibeli peni" ohun kekere to duro" timo gbagbo wipe o tọkasi eri atinuwa.

Olorun tun soro lati eri okan, lati ipongbe wa, ati ninu ohun to yagara sugbon e ma se iranti wipe ti Olorun ba soro, Oun To so man je ododo kode tako oro Re ti a kole. O sowon ki a gbo ohun Olorun, botile je wipe on sele, moti gbon ohun Olorun to yagara ni emeta tabi emerin ni aye mi, lekan lemeji ninu awon igba ti mo gbo ohun na ni igba ti monsun Ohun E siji mi nipa pipe oruko me"Joyce", sugbon momo wipe Olorun lon soro, koso idi pato tofi pemi sugbon momo ninú mi wipe On pemi fum idi tose pataki funn, botile je wipe koyemi fun aimoye odun.

Mofe fuyin ni iwuri pe kebe Olorun lati ran yi lowo lati gbo ohun Re ni ona kona toba Roo lati ba yin soro. O nife e; O ni eto to dara fun aye e, O fe ba o soro nipa awon nnkan wonyi.

Oro Olorun fun yi loni: Olorun soro ni ona topo; kan ranti- ko le tako Bibeli mimo.
Lati iwe gbigbo latodo Olorun lalaro lati owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 lati owo Joyce Meyer. Jade lati OroIgbagbo. Gbogbo ọtun wa ni ipamọ.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org