Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 2 nínú 14

Iranlọwọ mbe nìyí

Opolopo loti gba Jesu gege bi Olugbala ati Oluwa. Oma lo sorun, sugbon wonko fa isumo ekun Emi Mimo tonbe layé funwo tabi kiwon ri irírí aseyori ti Olorun fejekon gbadun ni ile aye. Ejeka sobayi, opolopo lonbe ni ona orun sugbon woóni gbadun irin ajo na.
Ama wo awon toni oro, agbara, ipo asowipe woni aseyori. Sugbon ọpọlọpọ awọn eniyan ti a kà si alaseyori lowa laìníni ayo, alafia ati itelorun ati awon ibukun miiran. Awọn iru eniyan bẹẹ niwonko ti ko eko lori bonse gbe okan le agbara Emi Mimo patapata.

Awon eni to simi le arawon ri sisimi le Olorun bi ami ailera. Sugbon oto beni wipe nipase fifa ipa Emi Mimo, wọn le ṣe pupo sii ni igbese aye wọn ju ti wọn le ṣe nipasẹ ṣiṣe ni agbara ara wọn lo.

Olorun dawa ni ona tojewipe tho ani agbara tiwa sibe ani ailera na tomuwa nilo iranlowo E.
Amo wipé Ofe ranwa lowo nitori I ran Oluranlowo atorunwa, Emi Mimo lati mma gbe inu wa.

Opolopo igba laman tiraka lainidi nitori akoti gba iranlowo tonbe laye funwa. Mo funyin ni iwuru loni wipe ke gbekele, dipo agbara yin. Ohun koohun ti e mba dojuko

Oro Olorun fun o loni: Ojo e to buru ju pelu Olorun oma daju ojo re ro dara ju laisi Olorun. Emi Mimo mbe niyi lati ba o soro ati lati ran o lowo ni ona gbogbo tio nilo iranlowo.

Lati inu iwe gbigbo latodo Olorun lolowuro lati owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 lati Joyce Meyer. Jade lati OroIgbagbo. Gbogbo Otun wa nipamo.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org