Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 14 nínú 14

Ikoro man diwo gbigbo ohun

Ikoro si Olorun je ni otito idiwo lati ma gbo ohun Re. Igbakigba ti ikoro bafe muo ni, ko sile. Aimoye igba, esu man fe jeka rope awa nikan lan la igba lile. Mi o fe dabi pe mo n banyin kedun sugbon kosi bi awon isoro na se leto, enikan tun mbe toni isoro juwa lo.

Arabirin kan nsise funmi ti oko re kosi sile ni igeyawo ogbon odun le ni mesan. O fi leta sile, osi kuro nile. Oje oun ibanuje fun! Mo gbega nigba towa sodo mi lehin ose melo toni," Joyce, gbadura funmi kin maba se were si Olorun". Esu ntan mi gidigidi kin sewere si Olorun. Mi o le sewere si Olorun. Oun nikan ni Ore timoni, Mofe iranlowo Re.

Ikoro fe joba si aye ore mi nitori aye e kolo bi otife kolo. Nigba taba farapa, a gbodo mo wipe gbogbo eniyan loni ife lati se oun toba wuwon atipe akole mu ife lati se oun toba wuwa siṣakoso- ani ninu adura. Ale gbadura si Olorun ko soro si awon tole farapawa; ale bere pe ki Olorun dari won lati se rere dipo ibi, sugbon isalẹ oro na ni Ogbodo fiwon le lati se oun toba wuwon. Ti eniyan ba se ohun to pawalara, koye ka da ebi le Olorun ki a ni ikoro Si.

Oro Olorun funyin loni ni, ti eba farapa ema da ebi le Olorun. Oun nikan ni ore otito ti eni.

Lati inu iwe gbigbo lati odo Olorun ti owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 ti Joyce Meyer. Jade lati OroIgbala. Gbogbo ọtun wa ni ipamọ.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org