Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Ibùgbé fun Emi Ọlọrun
Ti o ba je atunbi, o nírètí wipe Jesu n gbe ni inu e nipase agbara ti Ẹmi mimo. ìbéèrè nani, nje Ọlọrun wa ni ìtùnú nínú re? Nje O ni ibùgbé nínú e? Bi o tile je wipe Emi Ọlọrun mbe nínú re, awon ohun miiran n gbe nínú re, na - ohun bi ìfòyà, ìbínú, Owú jíjẹ, tabi kikùn ati àròyé sise.
Ọlọrun fummi ni àpẹẹrẹ iru bi ose ri fun Oun lati ni ibùgbé ni okan ti kikùn mbe, àròyé sise, ati àìnírépò n gbé. ká sọ pé o lo si ilé ọ̀rẹ́ e kan o si sowipe, "Oh, wa wole. Ma ba e mu ife kofí wa, ilé lowa seni ki o wa ni ìtùnú." nigbana ni, ore re bẹ̀rẹ̀ sini pariwo mo oko e ati awon mejeéjì n sin jágbe pelu fẹ̀fun won n si balo niwaju re. Bawo ni ọ́kàn re sema balẹ̀ ni iwaju iru gbọ́nmi-si-omi-òtó eyi?
Ti a ba fe je ibùgbé fun Èmí Oluwa' a gbodo jowo sile gbogbo ohun to n fa wa lati gbagbe nipa iwaju Re tabi tiwon je ohun ibínú. A gbodo dúró lati maa ráhùn, gbigba gbọ́nmi-si-omi-òtó laye ati àinisimi nínú wa, tabi gbigba ainìdáríjì. Kaka bee, a nilo lati mo daju wipe ìgbésí ayé inú wa n kopá ni awon ohun to múnú Ọlọrun dùn ati bu olá fún Ọlọrun. Ki enu wa kun fun iyín ati ìdúpẹ́. Ki a ji ni gbogbo ojo ka wipe ni ókàn wa, "E karo o, Oluwa. "Mofe je ki Ewa ni Ilè ki ọ́kàn Yin ko balẹ̀ loni".
Gbogbo wa nilo lati Ṣàkọsílẹ̀ awon ohun to n lo ni ókàn wa nitori ókàn wa je ibùgbé Olorun. Ti a ba ṣàyẹ̀wò ìgbésí ayé inú wa, aa si ma wo ile mimó ti Ọlọrun mu fun ibùgbé Re. E je ki a se àdéhùn lati mu ókàn Olorun bale nínú wa.
Oro Olorun fun o Loni: Se idaju wipe ibùgbé oni ìtùnú loje fun Ẹmi Oluwa.
Lati inu iwe gbigbo lati odo Ọlọrun ni owuro kookan nipasẹ Joyce Meyer. Àṣẹ oníṣẹ́ 2010 nipasẹ Joyce Meyer. Atejade nipasẹ OroÌgbẹ́kẹ̀lé Gbogbo awọn Ẹtọ wa ni ipamọ.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!
More
We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org