Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 6 nínú 14

Ọlọrun Yoo Mu Ẹmi Rẹ pada

Ni akoko diẹ ninu aye mi, Mo ba ohunkohun wi ti emi ko fẹ nitori pe mo ro pe o owa lati ọdọ eṣu. Moni wipe mobawí titi "Olubawi" mi fi gbó. Sugbon nigbati mo ṣàwárí wipe opploppo ohun timo bawí walati odo Ọlọrun. Pupo lara awon ohun timi ko feran tabi nife je awon ohun ti Ọlọrun gba laye fun ìdàgbàsókè mi.

òǹkọ̀wé Hébérù sowipe agbodo ubmit si ìbawí ti Olọrun. O bawa wí nitori O nife wa. Mase tiraka lati resist ohun ti Olorun lero lati lo fun dada e. Bere lowo Ọlọrun lati se ise to jinlẹ̀ pelu kúnnákúnná ninu e koobale je gbogbo ohun Tofe jeko je, se gbogbo ohun Tofe jeki o se, atipe kio ni gbogbo ohun Tio fe je ki o ni. Láàárín àkókò pdun ti nmo dènà gbogbo ohun tojomo ìrora tabi tolè koko, otito to rorùn niwipe mio dagba si ninu emi. Mo bere sini lo kakiri ati kakiri larin oke giga tipe kana (isoro). Ni igbeyin, mo rimowipe mon tiraka lati yẹra fún ìrora, sugbon mo ni ìrora na paapa. Ìrora lati wa bi ase wa tele o burú jù ìrora lati yìpádà lo.

Enì taje ni ẹmi wa (ọkàn, ìfẹ́ ọkàn, ati ìrònú), sugbon Lọ́pọ̀ ìgbà oti fara pa pelu ìrírí wa ni gbogbo agbaye. Ọlọrun se ileri lati da emi wa pada ti aba fọwọsowọpọ pelu ise ẹ̀mí mímọ́ ninu wa. Moni emi fifo tele, emi tiko ni àlàáfíà tabi ayo, sugbon Ọlọrun tisomidi odindin atipe Ofe iru ohun be fun o.

Oro Ọlọrun fun o loni: shi emi re si Ọlọrun pelu ki o bere lowo Re Kio wo gbogbo Ọgbẹ́ ati àpá e san.

Lati inu iwe Gbigbo Lati Odo Olorun Ni Gbogbo owuro lati owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 lati Joyce Meyer. Olùtẹ̀jáde ni OroIgbekele. Gbogbo Otun Wa Ni Ipamo.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org