Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 8 nínú 14

Gbigba Adura Ti Olorun

Molerope lara awon idi ti akin ni idaniloju ninu adura wa tabi wipe "aitisetan" lati gbadura lori oro kan niwipe an lo akoko lori ebe adura wa nikan soso.
Sugbon mowi funyi, ona todaju, toga ju, to munodoko ju: gbigba adura ti Olorun. Lati so ododo funyin, tinba gbadura temi, mole gbadura fun iseju medogun sibe koni dabipe motisetan; sugbon tinba ti Emi dari timo gbadura ti Olorun ni gbolohun meji pere itẹlọrun mawa fummi.
Mo wadi pe tinba gbadura ti Emi-dari, won ma rọrun pelu wantun kuru ju temilo. Won lo taara, won san oju abe niko. Okan mi bale wipe ise tise tinba gbadura ti Olorun kaka kingba adura mi. Ti aba gbadura tiwa ama foju si awon ohun ara ati ayidayida sugbon taba gbadura ti Olorun ama bere fun awon ohun ayerayei bi isodi mimo awon ero okan wa ati ise pelu ibasepo to jin pelu Olorun. Bere lowo Olorun pe Kio ko o biwonse gbadura E kaka kio gbadura tie waripe wa gbadun adura si.

Oro Olorun fun o loni: Gbadura ti Olorun kaka kio gbadura ti e.

Lati inu iwe gbigbo lati odo Olorun ni owuro lati owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 lati Joyce Meyer. Alakede ni OroIgbagbo. Gbogbo otun wa ni ipamo.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org