Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 9 nínú 14

Olorun soro nipase ẹbùn ati ipa

Awon eyan ni iyalenu, kiloye kinse pelu aye mi? Kini di timofi walaye? Se Olorun ni etó funmi?. Ona ti Olorun ngba dahun awon ibeere wonyi ni nipase talenti ati ipa. On dari wa lati loye idi nipase mimonse n ipa ti O funwa.

Talenti ti Olorun funni, abi alepeni "ebún", oje oun talese pelu irorun, ohun adayeba, Fun apere awon ayaworan mo bonse fi ìrísí ati awọ papo, nibe won feran latima ya nnkan, sculture and painting. Awon ako orin gbo orin ni ori won won sare ko melody ati/tabi oro orin na sile kiwon bale se orin ro rewa.
Awon elomiran ni natural abilith lati organize and adminiatative, awon elomi gifted ni gbigba eni ni iyanju, lati ran awon eyan lowo ni aye won ati ibasepo won. Nnkan kikan ti talenti wa baje, ama ni pleasure tanba se oun ti a natturally good at.

Toba mo idi tofiwa laye, mase oun to good at kowo Olorun fidi mule oun to good at nipase bibu blessing fun ise owo e. Mafi akoko sofo nipa gbingbin yonju latise oun tio lese, ti eniyan ba sise nibi tio gifted oma wa misrable-pelu awon to sumo won. Sugbin teyan bawa nibi toye kowa, oma jasi nibise oma je alabukun fun awon oga ati elegbe won.
Taba se oun tale se ama sense ami ororo Olorun(agbara ati iwalaye) ninu effort wa. Ama mope an operatee ninu gift wa eyi ma bu itin fun Olorun atipe aso iye si aye awon tosumowa. Olorun nsoro nipase ami ororo, On funwa lalafia ati ayo latimo wipe anmu etó E se laye wa.

Oro Olorun fun o loni: Se oun toó dafun latise, eyi ni gift Olorun fun o.

Lati inu iwe gbigbo latodo Olorun lolowuro lati owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 lati Joyce Meyer. Jade lati OroIgbagbo. Gbogbo Otun wa nipamo.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org