Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Idahun Àkókó
Nigba mííran o ma yamilenu bií aṣele ni ihaju nipo kan kiato ronu lati ba Olorun soro nipa e ati lati fetisi ohun E. Áwa ṣàròyé nipa awon isoro wa; áwa ráhùn; áwa nkun; áwa sofun awon ore wa; atun wa soro nipa bi asefe ki Olorun se nkan nipa e. Anihaju pelu ipo kan ni okun aya wa ati ninu wa, nigba kan kan aman kuna lati lo anfanni ojútùú to rọrun julọ: adura. Sugbon buri ju eyi lo ni, lẹhinna a ṣe boya ọrọ to yẹ̀yẹ́ ju ti eda mo: "odara, mo lero wipe gbogbo ohun timolese nani kin gbadura." odami loju pe eti gbo iru eyí ri tele atipe boya eti sori. Gbogbo wa tise. Gbogbo wa tijebi bi anse se si adura bi ipá ikehin atu so oro bi "odara, kosi ohun ton sise, boya kia gbadura." se emo ohun ti eyi sofunmi? Oso fummi wipe aafibe ni igbagbo ninu agbara adura boseye. Áwa gbe ẹrù ìnira ti a ko nilo lati ru - atipe ile aye lekoko ju boseye lo - Nitori a komọ̀ bi adura se lagbara si, taba mówe ni, ama ba Olorun soro atun fetisile lati gbo oun Tofe so nipa ohun gbogbo, kokinse gege bi ipinnu kehin, sugbon gege bi Ìgbésẹ̀ akoko.
Ọrọ Ọlọrun fún ọ lónìí: Jẹ ki adura jẹ Ìgbésẹ̀ akọkọ rẹ, kii ṣe ipinnu rẹ kẹhin.
Lati iwe gbigbo lati odo Ọlọrun ni owuro kookan nipasẹ Joyce Meyer. Àṣẹ oníṣẹ́ 2010 nipasẹ Joyce Meyer. Atejade nipasẹ OroÌgbẹ́kẹ̀lé Gbogbo awọn Ẹtọ wa ni ipamọ.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!
More
We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org