Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 7 nínú 14

Gbadura pelu ìdúpẹ́

ìdúpẹ́ se pataki pupọ lati ni anfani lati gbọ ohun Ọlọrun nitori, bi ìyìn ati ìjọsìn, o jẹ ohun ti Ọlọrun ṣe idáhùn si. O jẹ ohun ti Ọlọrun fẹràn, nkan ti o mu ọkan re lọ́yàyà. Igbakugba ti a ba fun Ọlọrun ni idunnu bii iyẹn, àjọṣe tímọ́tímọ́ wa pẹlu Rẹ mani àlékún si - ati pe o mu ki ibasepọ wa pẹlu Rẹ dara si.

Ti a ko ba kún fún ọpẹ́ fun ohun ti ani,Kílode tí O fi fún wa ni ohun miiran lati kún nipa? Ni apa keji, nigbati Ọlọrun bari wipè a mọrírì ore tọkàntọkàn pelu pe a kún fún ọpẹ́ fun awon ohun ńlá ati kékeré, O ma nìtẹ̀sí lati túbọ̀ bù kún wa pàápàá. Nìbámu pẹ̀lú Filippi 4:6, gbogbo ohun ti aba béèrè fun lowo Ọlọrun oye ki o ṣáájú ati tẹ̀ lé pelu ìdúpẹ́. Kosi ohun ki ohun ti a ma gbadura fun,oye ki ìdúpẹ́ ma tẹ̀ lé. ìwà to dara lati dagba ninu re ni ki a bere gbogbo adura wa pelu ìdúpẹ́. Àpẹẹrẹ eyi ma je: "Ẹ ṣeun fun gbogbo ohun ti Ẹ ti ṣe ni aye mi.Ẹrù jẹ̀jẹ̀ ni Yin atipe mo nifè ati mọrírì Yin gidigidi."

Mo gbà o níyànjú lati ṣàyẹ̀wò aye rẹ, lati fetisi ọrọ and ero rẹ, kii o wo oye ìdúpẹ́ ti o fi hàn.Ti o ba fe ipenija kan, tiraka lati koja jakejado odindin ojo kan lai sọ àsọjáde àròyé kan soso. Gbèrú ninu ìwà ìdúpẹ́ ni gbogbo Ipò. Kódà, kan kún fún ọpẹ́ pelu iyalenu- atipe ki o wo bi àjọṣe tímọ́tímọ́ re pelu Ọlọrun mani àlékún ati bi O se ma da ìbùkún ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ju ti tele lo.

Ọrọ Ọlọrun fun ọ loni: Sọ awọn ọrọ idupẹ, kii ṣe awọn ọrọ ẹdun.

Lati inu iwe gbigbo lati odo Ọlọrun ni gbogbo Owuro nipasẹ Joyce Meyer. Aṣẹkiko 2010 nipasẹ Joyce Meyer. Atejade nipasẹ OroIgbekele.Gbogbo awọn Ẹtọ wa ni ipamọ.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org