Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ ati Mìmọ̀lára
Ni ese bíbélì fun oni Olórun seleri lati ropo ókàn okuta pẹ̀lú ókàn eran ara. Ni oro keji, O le yi olọkàn lile di olọkàn fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ ati mìmọ̀lára
Ti aba fun Olórun ni aye wa, O ma mu làákàyè ti Òótọ́ ati òdì jinlè ninu ẹ̀rí ọkàn wa. Sugbon ti aba ṣọ̀tẹ̀ lodi sí ẹ̀rí ọkàn wa ni ọ̀pọ̀ igba, ale di olọkàn-lile. Ti iyen ba sele, a nilo lati je ki Olórun so ọkàn wa di fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ ki a ba le ni ìmọ̀lára ti ẹ̀mí fun ìdarí Èmí Mímọ́.
Moje olọkàn lile gidigan tele kin to bere sini ìfararora pẹ̀lú Olórun. Wíwá níwájú Re man mu ọkàn mi fẹ́lẹ́ atipe o mumi ni púpọ̀ ẹ̀mí-ìmọ̀lára si ohùn Re. Laisi ọkàn ìmọ̀lára si ifowó kàn ti Olórun, ako ni mọ̀ pé ọ̀pọ̀ igba On bawa sọ̀rọ̀. On sọ̀rọ̀ pelu pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, ni síbẹ̀, ohùn kékeré, tabi pẹ̀lú pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ ìdánilójú lori ọ̀ràn kan.
Olọkàn lile wa ni ewu lati pa àwọn ẹlòmíràn lara atipe won le ma mọ̀ dájú wipe won sebe, eyi sije ẹ̀dùn si ọkàn Olórun. Àwọn Olọkàn lile ati ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ "àwọn ton se ohun tiwon" won kole ni ẹ̀mí-ìmọ̀lára si ìfẹ́ tabi ohùn Re. Olórun feso àwọn ọkàn wa di fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ pẹ̀lú òrò Re, okàn lile kole gbo ohùn Re tabi gba àwọn opọ̀ ibukun To setan lati funwa.
Òrò Olórun fun o loni: Mu okán re fẹ́lẹ́ pẹ̀lú mìmọ̀lára si ohùn Olórun.
Lati inu iwe Gbigbo Lati Odo Olórun Làràárọ̀ Lati Owọ́ Joyce Meyer. Àṣẹ Oníṣẹ́ 2010 lati ọwọ́ Joyce Meyer. Atejade nipasẹ Òròìgbẹ́kẹ̀lé. Gbogbo awọn Ẹtọ wa ni ipamọ.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!
More
We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org