Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní

2 Oṣù Ọ̀wàrà 2025

1 Kronika 16:34 - Fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó dára;
ìfẹ́ ẹ rẹ̀ dúró títí láé.
Pín
1 Kronika 16:34 - Fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó dára;
ìfẹ́ ẹ rẹ̀ dúró títí láé.
Pín
1 Kronika 16:34 - Fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó dára;
ìfẹ́ ẹ rẹ̀ dúró títí láé.
Pín
Èyí tó kànÈyí tó kàn
Fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó dára; ìfẹ́ ẹ rẹ̀ dúró títí láé.

1 Kronika 16:34 (YCB)

Kà 1 Kronika 16:34
Fọwọ́ síi

Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó wà fún ọ̀sẹ̀ yìí

1 Oṣù Ọ̀wàrà 2025

Ó ń tọ́ àwọn agbo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn: Ó kó àwọn ọ̀dọ́-àgùntàn ní apá rẹ̀. Ó sì gbé wọn súnmọ́ oókan àyà rẹ̀; ó sì fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ darí àwọn tí ó ní.

Isaiah 40:11 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 1 Oṣù Ọ̀wàrà 2025 - àwòrán 0

30 Oṣù Owewe 2025

Àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá sí ìmọ́lẹ̀ rẹ, àti àwọn ọba sí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ rẹ.

Isaiah 60:3 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 30 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 1

29 Oṣù Owewe 2025

Nítorí Ọlọ́run kan ní ń bẹ, onílàjà kan pẹ̀lú láàrín Ọlọ́run àti ènìyàn, àní Kristi Jesu ọkùnrin náà. Ẹni ti ó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà fún gbogbo ènìyàn—ẹ̀rí tí a fi fún ni ní àkókò tó yẹ.

1 Timotiu 2:5-6 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 29 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 2

28 Oṣù Owewe 2025

Èmi yóò fún yín ni ọkàn tuntun, èmi yóò sì fi ẹ̀mí tuntun sínú yín; Èmi yóò sì mú ọkàn òkúta kúrò nínú yín, èmi yóò sì fi ọkàn ẹran fún yín.

Esekiẹli 36:26 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 28 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 3

27 Oṣù Owewe 2025

nítorí náà ìsinmi kan kù fún àwọn ènìyàn Ọlọ́run.

Heberu 4:9 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 27 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 4

26 Oṣù Owewe 2025

Àwọn tí ó jẹ́ ọlọ́gbọ́n yóò máa tàn bí ìmọ́lẹ̀ ọ̀run, àti àwọn tí ó ń tọ́nisọ́nà sí òdodo, yóò máa tàn bí ìràwọ̀ láé àti láéláé.

Daniẹli 12:3 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 26 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 5
Ṣe Ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò náà

Gba Bíbélì ọ̀fẹ́ ti orí ayélujára fún fóònù àti tábúlẹ̀tì.

Gbá ohun èlò ti Bíbélì ìsisìyíwàyí
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò