Ètò Ọlọ́jọ́ Mọ́kànlélọ́gbọ̀n fún Àtúntò ÌgbéyàwóÀpẹrẹ

31 Day Marriage Reset

Ọjọ́ 3 nínú 31

Ṣé ó n gbìyànjú láti jẹ aláyọ̀, aláàánú, onísúùrú, ọlọ́rọ̀ tútù, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ? Tí Kò bá rí bẹ́ẹ̀, ǹjẹ́ o leè gbìyànjú láti bẹ̀rẹ̀ loni àti ní ọjọ́ rẹ gbogbo tó kù.

•••

Kini ohùn náà tí olólùfẹ́ rẹ fẹ́ràn? Ṣé kọfí ni? Ṣé tíì ní? Ṣé hamburger ni? Ṣé tacos ni? Ṣé ìrìn ni? Ṣé ludo ní? Ṣé àkíyèsí àwọn nǹkan wọ̀nyẹn kí ó sì lọ í pèsè wọ́n. Bá wọn ṣe ife kọfí kan. Pẹ̀lú wọn jọ rìn káàkiri. Yan ohùn kan láti ṣe tí yóò jẹ́kí wọ́n mọ̀ wípé ẹ bìkítà fún wọn àti pé ìbásepọ̀ yín kìí ṣe tí ìrọ̀rùn nìkan ṣùgbọ́n dípò bẹ́ẹ̀ ó dà lórí ìfẹ́-àtinú-wá láti ṣe ìkẹ́ wọn. Inúrere kò fi bẹ́ẹ̀ rọrùn ni gbogbo ìgbà, ṣùgbọ́n ó níye lórí ní gbogbo ìgbà... paapaa nínú ìgbéyàwó. Ẹ̀ dí ọwọ́ ara yín mú nínú ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ yín. Ẹ̀ fi ẹnu kò ara yín lẹ́nu tí ẹ́ bá gúnlẹ̀, àti òmíràn tí ẹ́ bá fẹ́ gbéra àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ bẹ́ẹ̀ nígbàkigbà. Ẹ̀ dímọ́ ara yín fún ìgbà pipẹ́. Ẹ bára mọ́ ara, wọ́ ara. Ẹ wà fún ara yín ní ìgbà gbogbo.

Báwo ni ó ṣe lè ṣe ju bí ó ṣe rọrùn fún ọ loni láti ṣe ohun tó dára?

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

31 Day Marriage Reset

Ǹjẹ́ o nílò ohun tí yíò mú kí ìgbéyàwó rẹ sunwọ̀n sí i? Ẹ ka Ìwé Mímọ́, kí ẹ sì bá ara yín jíròrò fún ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n gbáko, ẹ ó sì rí bí Jésù yíò ṣe fi ara hàn yín!

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Stonecreek fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: http://www.stonecreek.church