Ètò Ọlọ́jọ́ Mọ́kànlélọ́gbọ̀n fún Àtúntò Ìgbéyàwó

Ètò Ọlọ́jọ́ Mọ́kànlélọ́gbọ̀n fún Àtúntò Ìgbéyàwó

Ọjọ́ 31

Ǹjẹ́ o nílò ohun tí yíò mú kí ìgbéyàwó rẹ sunwọ̀n sí i? Ẹ ka Ìwé Mímọ́, kí ẹ sì bá ara yín jíròrò fún ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n gbáko, ẹ ó sì rí bí Jésù yíò ṣe fi ara hàn yín!

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Stonecreek fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: http://www.stonecreek.church