Ètò Ọlọ́jọ́ Mọ́kànlélọ́gbọ̀n fún Àtúntò ÌgbéyàwóÀpẹrẹ

31 Day Marriage Reset

Ọjọ́ 15 nínú 31

“Mo ní ìfẹ́ rẹ síbẹ̀.” Ìwà Ọlọ̀run ni èyí. 

•••

Láì bìkítà ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ní àná. Láì bìkítà ohun tí a sọ tàbí ohun tí a kò sọ. Láì bìkítà bí a bá tọrọ ìdáríjì lẹ́hìn ìṣe náà tàbí rárá. Àwọn àánú Rẹ̀ jẹ́ ọ̀tun ní òwòwúrọ̀. Ó ṣe tàn nígbàkúùgbà láti dáríjì wá. Eléyìí kò dá lórí ìwà rẹ, ṣùgbọ́n nítorí èyí ni ìwà Rẹ̀. Èyí ni àpẹẹrẹ tí Ó fi lélẹ̀ fún wa. Ó fẹ́ dáríjì wá kí ó ṣe àánú fún wa ní ìgbà gbogbo. Èyí ni àpẹẹrẹ tí ó yẹ kí a tẹ̀lé. 

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

31 Day Marriage Reset

Ǹjẹ́ o nílò ohun tí yíò mú kí ìgbéyàwó rẹ sunwọ̀n sí i? Ẹ ka Ìwé Mímọ́, kí ẹ sì bá ara yín jíròrò fún ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n gbáko, ẹ ó sì rí bí Jésù yíò ṣe fi ara hàn yín!

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Stonecreek fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: http://www.stonecreek.church