1
Mika 3:8
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi kún fún agbára pẹ̀lú ẹ̀mí OLúWA, láti sọ ìré-òfin-kọjá Jakọbu fún un, àti láti sọ ẹ̀ṣẹ̀ Israẹli fún un.
ប្រៀបធៀប
រុករក Mika 3:8
2
Mika 3:11
Àwọn olórí rẹ̀ ń ṣe ìdájọ́ nítorí àbẹ̀tẹ́lẹ̀, àwọn àlùfáà rẹ̀ sì ń kọ́ni nítorí owó ọ̀yà àwọn wòlíì rẹ̀ pẹ̀lú sì ń sọtẹ́lẹ̀ nítorí owó. Síbẹ̀, wọn gbẹ́kẹ̀lé OLúWA, wọ́n sì wí pé, “Nítòótọ́, OLúWA wà pẹ̀lú wa! Ibi kan kì yóò bá wa.”
រុករក Mika 3:11
3
Mika 3:4
Nígbà náà ni wọn yóò kígbe sí OLúWA, Ṣùgbọ́n òun kì yóò dá wọn lóhùn. Ní àkókò náà ni òun yóò fi ojú rẹ̀ pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ wọn, nítorí ibi tí wọ́n ti ṣe.
រុករក Mika 3:4
គេហ៍
ព្រះគម្ពីរ
គម្រោងអាន
វីដេអូ