Mika 3:11
Mika 3:11 YCB
Àwọn olórí rẹ̀ ń ṣe ìdájọ́ nítorí àbẹ̀tẹ́lẹ̀, àwọn àlùfáà rẹ̀ sì ń kọ́ni nítorí owó ọ̀yà àwọn wòlíì rẹ̀ pẹ̀lú sì ń sọtẹ́lẹ̀ nítorí owó. Síbẹ̀, wọn gbẹ́kẹ̀lé OLúWA, wọ́n sì wí pé, “Nítòótọ́, OLúWA wà pẹ̀lú wa! Ibi kan kì yóò bá wa.”