Mika 3:4

Mika 3:4 YCB

Nígbà náà ni wọn yóò kígbe sí OLúWA, Ṣùgbọ́n òun kì yóò dá wọn lóhùn. Ní àkókò náà ni òun yóò fi ojú rẹ̀ pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ wọn, nítorí ibi tí wọ́n ti ṣe.