Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 13 nínú 14

Ewa ni ìrètí

Agbara Olorun man sokale ti aba gbadura ni igbagbọ, ninu igbekele ati igbagbo, nitori igbagbo telorun. ìrètí je eroja si igbagbọ to gbe agbara titie- agbara ìrètí. Ibagbọ man de ọdọ ibugbe emi lati rètí agbara emi Olorun lati sokale latise oun ti eniyan kan laye ole se.

Iyemeji, nida keji, on beru pe kosi oun tomasele; kote Olorun lorun kodekin se oun tole sure fun.
Akin se alagbara tanba gbe pelu iyemeji, ijakule, ati aini igboya ninu Olorun.
Ro igba kan tio rope Olorun o ni yoju fun o, oole gbadura tolagbara, sebi? Nisin ranti igba ti okan e gbekele Olorun patapata tio ni igbagbo pe Yo yoju fun o, ole gbadura toni agbara, sebi? Agbara ireti ninu adura niyen, ani bi nnkan o balo dede biase lero pe oma ri, nigbekele ninu Olorun lati mo itodarajulo atipe kio ma reti E latise awon oun tolagbara.

Oro Olorun fun oloni:: Ma reti Olorun lati se oun alagbara ni aye e kio de gbadura pelu igboya.

Lati inu iwe gbigbo latodo Olorun lolowuro lati owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 lati Joyce Meyer. Jade lati OroIgbagbo. Gbogbo Otun wa nipamo.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org