Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 11 nínú 14

E yìn ni òna yin wo Iwaju Re

Òna pupo mbe ti ale fi fi arawa laye lati gbo ohun Olorun ọkan ninu re ni lati wo inu iyin ati ìjọsìn towotowo. Didùn inu Olorun ni lati fi agbara E ati ifarahan E han si awon eniyan ton yin pelu awon ton sín ni toto. Nigbati ti ifarahan ati agbara E bade ama gbo Ohun Re, ama ri ise iyanu, iwosan ma sele si awon eniyan, aye yio yipada, iyipada ma sele lati inu wa sode.

Se kosi ninu awon ohun to fe ninu ibasepo re pelu Olorun? ti aba Ba soro ti ansi fetisi ohun Re, se on gbadura nipataki nitori ofe iyipada otun
ni awon agbegbe aye e? Ti o mba mbere fun ise tuntun iyipada niyen, ti o mba gbadura ki eniti o feran wa sodo Olorun, iyipada niyi. Ti o ba mba gbadura fun Olorun lati fi ara E han si kio le dagba si ni didagba emí, iyipada na ni eyi. Ti o mba gbadura ki odomode tin gbe ni isale opopona ile re yema lo ogun oloro mo, iyipada noni. Ti o mba gbadura ki Olorun ba e mu ibinu re lole, iyipada noni.

Ohunkohun ti on gbadura fun, ona to dajulo latibere ni pelu iyín ati ìjọsìn. Wonyo mu okan e totun pelu olorun pelu wonyo si ona fun e lati gbo ohun Re ki iyipada le sele.

Oro Olorun fun o loni ni: To ba fegbo ohun Olorun, yin kio sín

Lati inu iwe gbigbo lati odo Olorun ti owo Joyce Meyer. Aṣẹkikọ 2010 ti Joyce Meyer. Jade lati OroIgbala. Gbogbo ọtun wa ni ipamọ.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org