Gbigbo lati odo Olórun làràárọ̀Àpẹrẹ

Hearing From God Each Morning

Ọjọ́ 12 nínú 14

Olorun mba awon Òré E soro

Boya kosi eni tia tokasi pe oun ni "ore Olorun" ju Abrahamu. Nigbati Bibeli tokasi Dafidi gege bi "okunrin lehin okan Olorun" ati peteru bi "omo eyin ti Jesu feran julo"
Abrahamu ni ọlá todayàtọ fun jije ore Olorun ju ibi kanlo ninu Iwe Mimo.

Nigbati Olorun setan lati gbe idajo dide lori iwa buburu awon eniyan Sodomu ati Gomora, Oso fun Abrahamu eto Toni.

Ni oresise, awon eyan sofun arawon nipa eto tiwon fese. Nitori Olorun ri Abrahamu gege bi ore E, Oso oun ti ofese fun u-gege bi iwo yo so fun ore e oun tofese, nigbati Abrahamu ri idajo nla ti Olorun fe gbelu Sodomu ati Gomora,o" sumo o ni', Se wa pa awon olododo re mo awon eyan buburu? (Genesisi 18:23 NKJV). Gege bi Olorun se pin eto E pelu Abrahamu nitori wonje ore ara, Abrahamu "Sumo" Olorun Osi soro sode pelu igboya nipa eto re-nitori wonje ore. Woni ibasepo tiwon lesoro larọwọto; iru ibasepo ti Abrahamu ni pelu Olorun jeyo lati inu ipamo ife E.wonle soro sita. Iru ibasepo ti abrahamu gbadun pelu Olorun walati ipamo ninu ife.

Olorun feje ore e, na, Ofe ba o soro pelu Ofe gbo awon ohun tofe san Fun.
Bere loni lati gba ona tuntun pe iwo je ore Olorun kio si bawi gege bi ore E.

Oro Olorun fun oloni:Ma dagba ninu ibasepo re pelu Olorun tio le fibasoro larowoto atipe yo gbo ohun Tofe so fun o.

Lati inu iwe gbigbo latodo Olorun lolowuro lati owo Joyce Meyer.Aṣẹkikọ 2010 lati Joyce Meyer. Jade lati OroIgbagbo.Gbogbo Otun wa nipamo.. Copyright 2010 by Joyce Meyer. Published by FaithWords. All rights reserved.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Hearing From God Each Morning

Ni ode siiyin ariwo yiwaka. Ariwo to yiwaka man bori wa, awon omo wa, awon ore wa, aya tabi oko wa, ati awa papa. Awon ariwo yi ti fa idiwo, toje wipe ati gbagbe ohun to se pataki julo-Ohun Olorun. Eto yi mu nikekere iranti tolagbara toma mu imoriya ati pe yoo ron o lowo lati pese akoko fun Olorun eni tose pataki julo, dagbasoke ninu ife lati ni ipade ojojumo pelu Re, Maani oye si awon idahun Re si awon adura re, ati kio tun mojuto ibasepo re pelu awon elomiran bio tin ni ipade tiwo nikan pelu Olorun. Bere ojo re pelu eni ti kokinse pe onifere nikan ju biose lero lo sugon Otun ni idahun si gbogbo ibere ti o leni!

More

We would like to thank Joyce Meyer Ministries for providing this reading plan. For more information, please visit: www.joycemeyer.org