Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN IMỌLẸ NÁÀ
A n'reti Mesaya!
KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Jésù ni Olùgbàlà, Mesaya, Ọmọ-ọmọ Dáfídì!
Luku 1:32, 69 ati Iwe Ìfihàn 22:16
DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN
Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ati sọ tẹlẹ nípa wíwá rẹ̀ fún ẹgbẹgbẹrun ọdún! Ṣe ìrántí àwọn ọpọlọpọ asọtẹlẹ nípa bibọ mesaya. Ronú nípa ifẹ nlá Ọlọrun sí ọ..
Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ale mimo "

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org