Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN IMỌLẸ NÁÀ
A n'reti Mesaya!
Njẹ́ o tubo rí ara re bíi àgùtàn sí Ọlọrun lónì?
KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Ọba Olùgbàlà kan mbọ̀!
Sakaraya 9:9-11
DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN
Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ènìyàn kò le pa òfin Ọlọrun mọ, Majẹmu òdodo rẹ̀. Àní láti ta ẹjẹ sílẹ̀ fún Idarijin ẹsẹ. Na àkókò díẹ̀ láti jewo ẹsẹ kí o si dupẹ lówó Ọlọrun fún ẹjẹ Majẹmu tí o kọwa yọ nínú ọfin.
Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ayo sí àgbáyé"

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org