Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN IMỌLẸ NÁÀ
Ọjọ Mesaya ti sunmọ!
Ṣe o rántí ìgbé ayé tí o gbé kí o tó mọ Kristi
KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Abii láti ọwọ wúndíá
Matiu 1:18-25
DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN
Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Abi Jésù nípasẹ wúndíá kan. Kíni ìdí tí o ṣe ṣe pàtàkì? Jésù jẹ ènìyàn ní kíkún, o si jẹ́ Ọlọrun ní kíkún - kò sí ẹ̀dá tí o jẹ́ béè
Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Alé idakẹ rọrọ" ati "Nínú ibujẹ ẹran"

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org