Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 26 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

Mesaya ti wà níbí!

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
A jẹrisi Majẹmu atijọ àti Titun pẹ̀lú ẹjẹ
Eksodu 24:3-8 ati Luku 22: 19-20

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Àbí Jésù láti jẹ́ ìrúbo pípé. O gbé ayé ai lese, o sì gba ìjìyà tí o tó si ẹ̀ṣẹ wa. Sùgbón se a dupe lówó rẹ?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Fi adé púpò dé e"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 25Ọjọ́ 27

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org