Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 23 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Kíni ìdí tí a se nilo Majẹmu titun? Kíni ìdí tí a se nilo Olùgbàlà?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu Titun: Ọkàn Titun àti emi titun
Ìsíkíẹlì 36:25-29

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ̀
Majẹmu Titun wá pẹ̀lú ọpọlọpọ àwọn Ẹ̀bùn. Kíni àwọn Ẹ̀bùn yí? Báwo ni àwọn Ẹ̀bùn yìí o ṣe mú kí àwọn ènìyàn Ọlọrun yatọ?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì làti júbà, jewo, yin, kí o sí dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ìlú kékeré ti Betilehemu"

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org