Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN IMỌLẸ NÁÀ
A n'reti Mesaya!
Ìfẹ Ọlọrun láti ìbèrè ni fún ọ!
KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu Titun kán mbọ̀
Jeremaya 31:31-34
DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN
Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Majẹmu atijọ nilo ìrúbo ọdọọdún. Nínú Majẹmu Titun ìrúbo pípé ẹẹkan wà fún gbogbo ènìyàn. Ṣe o gbẹkẹle nínú ìrúbo pípé ti Jésù?
Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ẹwà, gbogbo ẹyin olotito"
A n'reti Mesaya!
Ìfẹ Ọlọrun láti ìbèrè ni fún ọ!
KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu Titun kán mbọ̀
Jeremaya 31:31-34
DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN
Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Majẹmu atijọ nilo ìrúbo ọdọọdún. Nínú Majẹmu Titun ìrúbo pípé ẹẹkan wà fún gbogbo ènìyàn. Ṣe o gbẹkẹle nínú ìrúbo pípé ti Jésù?
Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ẹwà, gbogbo ẹyin olotito"
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org