Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 25 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

Mesaya ti wà níbí!

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Olùgbàlà kan, tí o jẹ́ Kristi Olúwa
Luku 2:1-21

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Jésù, Ìbùkún sí gbogbo orilẹ èdè
Wòlíì, Àlùfáà àti Ọba
Imusẹ Majẹmu atijọ, Ònkòwé ati Olutọju Majẹmu Titun
Wòlíì tí o tóbi jù lọ, Àlùfáà àgbà tí o tóbi jù lọ, Ọba àwọn ọba.

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Àwọn angẹli láti ibùgbé ògo" àti "Ayọ̀ sí gbogbo àgbáyé

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 24Ọjọ́ 26

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org