Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN ÌMÓLÈ NAA
A n'reti Mesaya!
Kíni ohun kàn ti iwọ kọ nipa Jésù lana?
KA AWON ESE BÍBÉLÌ YÍ
Oluṣọ-agutan ọba kan
Ìsíkíẹlì 34:20-24
DÁHÙN NÍNÚ IJỌSIN
Ṣe ijọsin pelu ayé rẹ.
Bi Dáfídì se ṣe itọju àwọn àgùtàn rẹ bẹni Jesu nṣe itoju. Sọ nípa bí olùṣọ àgùntàn se nṣe itoju fún àwọn àgùntàn.
Bawo ni Jesu se ntoju wa?
Ṣe ijọsin pẹ̀lú adura.
Lo ẹsẹ bíbélì láti júbà, jewo, yín àti dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ijọsin pẹlu orin
Kọ "eeṣe akọkọ"
A n'reti Mesaya!
Kíni ohun kàn ti iwọ kọ nipa Jésù lana?
KA AWON ESE BÍBÉLÌ YÍ
Oluṣọ-agutan ọba kan
Ìsíkíẹlì 34:20-24
DÁHÙN NÍNÚ IJỌSIN
Ṣe ijọsin pelu ayé rẹ.
Bi Dáfídì se ṣe itọju àwọn àgùtàn rẹ bẹni Jesu nṣe itoju. Sọ nípa bí olùṣọ àgùntàn se nṣe itoju fún àwọn àgùntàn.
Bawo ni Jesu se ntoju wa?
Ṣe ijọsin pẹ̀lú adura.
Lo ẹsẹ bíbélì láti júbà, jewo, yín àti dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ijọsin pẹlu orin
Kọ "eeṣe akọkọ"
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org