Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN ÌMỌ́LẸ̀ NÁÀ
Àá ń retí Mèsáyà!
KÀÀ ÀWỌN ẸSẸ̀ BÍBÉLÌ YÌÍ
Ọba kan tí yóò jọba lórí ìtẹ́ẹ Dáfídì láíláí
Isaiah 9:6-7
DÁHÙN PẸ̀LÚ ÌJỌSÌN
Jọ́sìn Pẹ̀lú Ayé Rẹ
Tún àwọn orúkọ olùgbàlà mẹ́rẹ̀rin tio wá ní ẹsẹ̀ kẹfà kà. Ìtumọ̀ wo ni ọ̀kànkan nínú rẹ̀ ní síọ? Kíni ìrísí rẹ nípa Jésù Ọba nínú orúkọ kàǹkan?
Jọ́sìn Pẹ̀lú Àdúrà
Loo Bíbélì láti júbà, jẹ́wọ́, yìǹ, àti dúpẹ́ lọ́wọ́ Olúwa.
Jọ́sìn Pẹ̀lú Orin
Kọrin, "Ẹwá ká jọ júbà rẹẹ̀."

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org