Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN IMỌLẸ NÁÀ
A n'reti Mesaya!
KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu Ọlọrun pẹlu Dáfídì
Orin Dáfídì 89:1-4
DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN
Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ọlọrun se àfihàn ìdúróṣinṣin ifẹ ati òtítọ rẹ. Wá ìtumò ifẹ ati òtítọ nínú ìwé ìtumò Bíbélì, ki ọ sí jíròrò nipa bí Ọlọrun se ṣàfihàn rẹ sí ọ àti ìdílé rẹ.
Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Tayọ, tayọ, lafi júbà rẹ"

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org