Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 16 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Báwo ni ayé rẹ ṣe tán òjíjí ẹrù Oluwa?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ

Majẹmu Ọlọrun pẹlu Dafidi
2 Samuẹli 7:8-17

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Làti ìdílé Dafidi ni ọba ayérayé yóò ti wá. Ṣe ayé rẹ ṣàfihàn ifẹ rẹ fún Ọba Jésù? Sọ fún okankan ìdílé rẹ bí wọn ọ ṣe sin Jésù.

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Wá, Jésù tí a tí n'reti "

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org