Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 15 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Báwo ni o ṣe gbẹkẹle agbára Èmí Mimo lai gbẹkẹle agbára tirẹ lóòní?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Isọtẹlẹ Mesaya, o ga jù Dáfídì
Isaiah 11:1-10

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
É ká laini kọọkan ti o wa ni ẹsẹ keji ati iketa sókè. Nje ìdùnnú rẹ wà nínú ẹru Oluwa? Jíròrò bi èyí yóò ṣe rí nínú ayé rẹ

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Awọn angẹli kọrin"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 14Ọjọ́ 16

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org