Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 14 nínú 91

TAN ÌMÓLÈ
A nreti Mesaya!

KA ẸSẸ BÍBÉLÌ
Ọba àti ìjọba kan nbọ! Dáfídì, ọba tí a fi àmì òróró Yàn.
1 Samueli 16:4-13

DÁHÙN PẸLU ÌJỌSÌN

Se ìjọsìn pẹlu ayé è rẹ
Emi Olorun dabo Dáfídì. Emi mimo ma nmu wa ṣe ohun tí Ọlọrun pe wa lati se. Báwo la ṣe lè gbẹkẹle agbara emi mimo, Lai gbẹkẹle agbara tiwa?

Se ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ bíbélì láti júbà, jewo, yin ati dupe lowo Olorun.

SE ÌJỌSÌN PẸLÚ ORIN
Kọ orin "Angẹli a ti gbọ níbi gíga"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 13Ọjọ́ 15

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org