Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 13 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Pétérù Wasu Jésù, wòlíì Ọlọrun tí a ti ṣèlérí
Ìṣe àwọn àpọsítélì 3:17-26

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹ̀lú ayé rẹ
Ọlọrun wípé kí a fetísílẹ̀ sí wòlíì bíi Mósè. Ṣe iwọ ma nfi eti sí àti gbọràn sí Jésù? Àwọn adari nígbà Jésù ko se idanimo rẹ. Sibẹ wọn o ṣe ìṣirò iṣe wọn. Gbé ìgbé ayé ìwà mimọ, pẹlú irẹlẹ yípadà kúrò nínú àwọn ẹsẹ aimọ.

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ayò sí gbogbo ayé"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 12Ọjọ́ 14

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org