Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 12 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Ṣe o rántí ọrọ nla ti Ọlọrun ntoju?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Samuẹli, Wòlíì àti àlùfáà
1 Samuẹli 3: 19-20 àti 1 Samuẹli 7:5-17

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ọlọrun bá Israẹli sọrọ nípasẹ Samuẹli. Kò sí ẹni tí ọ le ṣe ìgbọràn sí òfin ní pípé. Ọdọ àgùntàn tí ọ pe ni wọn fi se ìrúbo fún Idarijin ẹsẹ. A nilo olùgbàlà!

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ilu kékeré e tí Bethlehemu"

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org