Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 11 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Bawo ni ayé rẹ ṣe tán ògo Ọlọrun bí o ṣe nna àkókò pẹ̀lúu rẹ?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Wòlíì bi Mósè
Deuteronomi 18:18 àti 34:10-12.

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Mósè mo Ọlọrun ní ikọkọ ati pẹlu agbára. Eni tí o jẹ Ọlọrun nìkan ló jẹ wòlíì tí o tóbi ju Mósè lọ: Jesu-Kristi, Ọmọ Ọlọrun alààyè!

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Noeli Akọkọ"

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org