Wíwá Àlàáfíà Nínú ÌdúróÀpẹrẹ

Wíwá Àlàáfíà Nínú Ìdúró

Ọjọ́ 7 nínú 7

Ojó Keje: Àkókò Olórun

"Èyí tí ó kéré jù nínú yín yóò di ẹgbẹ̀rún kan, èyí tí ó kéré yóò di orílẹ̀-èdè ńlá.Èmi ni Olúwa;ní àkókò rẹ̀ Èmi yóò ṣe èyí.” Isaiah 60:22 (AMP)

Àsìkò ni gbogbo ǹkan. Kíni ó mú àkókò kan pàtó dì àkókò tí ati yàn:

  • Ọ̀nà ìrọ̀rùn tí ógbà selè- Nígbàtí Olórun bá wà níbè ó nílọ̀ ìlàkàká láti rí gbà nítorí tí ón jáà fún ọ osiń mú ohun gbogbo sisé pò fún rere rẹ. Bí ó bá rí ojúrere gbà lódò Olórun kòsí ohunkóhun kan tí á dá tí ó lè fi ojú ibi wò ọ.
  • Ìlérí rè ti yóò pé- Olórun dúró lórí isé ìyanu tíó wà títí láì, tí kìí ṣe eléyìí tí ó wà fún ìgbà díẹ̀, fún ìdí èyí ó dára láti dúró.
  • Títóbi isé ìyanu rè- Olórun máà ńfé kí isé ìyanu rè já sí ògo ọ̀hun nípa ṣíṣe ohun tí ẹnìkan kan kólé ṣe, ronú re jinlẹ̀ Olórun ńfé ìgbékẹ̀lé rẹ pátápátá.
  • Ìbáṣepọ̀ pèlú àwọn ẹlòmíràn- Olórun kìí bùkún enití kòní ìbáṣepọ̀ pèlú àwọn ẹlòmíràn, ó máa ń sáábà jé ìrọ̀ inú Olórun tí ó ga jùlo láti kó ipa rere nínú ayé òpòlopò àti pàápàá tí ìran tí ó ńbọ̀. Àkókò Olórun ní àkókò tí ó tó, àkókò tí ó sí tó ní àsìkò tíó dára jùlo. Dúró ní ìrètí kí ó sì ní ìgbàgbọ́. Kòsí àkókò tí a lò pèlú Olórun tí ó sófọ̀. Àsìkò ìpalèmọ̀ ṣe pataki gégébí ìfarahàn náà ṣe ṣe pàtàkì. Ìpalèmọ̀ ṣe pàtàkì sí Olórun ju ìlérí lo, fún ìdí èyí ẹjé kí á gbọràn títí dí àkókò ìmúse Olórun. Ní àkókò ìdúró sọ ìrora rẹ di ìdí láti ṣe òun rere ní ayé àwọn ẹlòmíràn. Máṣe jé kí ìrora rẹ já sí asán. Ìwé àṣàrò yìí ńṣe àpẹẹrẹ bíbí ìdí pàtàkì jade kúrò nínú àkókò ìdúró, ṣe àwárí ìdí pàtàkì tí Olórun féé mú jáde nínu àkókò ìdúró rẹ kí ọ sì dúró de àsìkò Olórun.

Àròjinlẹ̀:

Àwọn ohun tí ase àkọsílẹ̀ rè nínú ìwé àṣàrò yìí jé díè níní ìdí tí a fi nílọ̀ láti dúró de àsìkò tí ó tóo. Ǹjé ọ lè ronú lori àfikún míràn.

Nípa Ìpèsè yìí

Wíwá Àlàáfíà Nínú Ìdúró

Ní ìgbà kan tàbí òmíràn, gbogbo ènìyàn gbódò ní ifòrítì ní àsìkò ìdúró. Ní ìgbà àti àsìkò tí mo wà nínú ìdúró,mo se àwárí agbára tí ó wà nínú òrò Olórun àti àwọn ẹrí ti ó runi sókè láti ẹnu àwọn ènìyàn kan láti gbé ìgbàgbọ́ mi ró ṣinṣin. É dara pò pèlú mí nínú ìrìn àjò olójó méje níbi tí aó ti fi agbára tí ó wà nínú dídúró ní idakẹrọrọ àti ìrètí fara mọ àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Olórun tí kìí yẹ̀ lái nípa ìlérí rè. Ẹjé kí á gba agbára àti ìtùnú láti inú òrò Olórun.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Omoyemi Ojo fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: mywaitingroom.co.uk