OHUN KANÀpẹrẹ

OHÚN KAN yìí sì ni ìbásepọ̀ wa pẹlú Jésù Krísti.
A sì ti ṣe àyẹ̀wò kọ́kọ́rọ́ 5 tí a fi nwá OHÚN KAN yí:
- BÉÈRÈ
- ṢE ÀWÁRÍ
- GBÉ INÚ
- TẸJÚ MỌ
- ṢE ÌWÁDÌÍ
Ẹ̀ jẹ́ kí n gbà yín níyànjú bí a ṣe n mú ifọkansin yi wá sí òpin. Fí ẹ́sẹ̀ ìwé-mímọ́ yi ṣe ígbé ọkàn rẹ. Kàa ní ọ̀pọlọpọ àwọn ẹlẹ́ka-jẹ̀ka Ìwé Mímọ́. Jẹ́ kó jẹ́ àkọ́sórí fún ọ. Ṣé àtúnkà rẹ ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ igba.
Nítorí wípé ìgbésí ayé rẹ yíò yípadà nípasẹ ádùrá yìí.
'OHÚN KAN li èmi ntọrọ ni ọdọ̀ Olúwa,
ohun náà ni èmi yiò máà WÁ KIRI:
kí èmi ki o lé máa GBÉ INÚ ilé Olúwa
ní ọjọ ayé mí gbogbo,
kí èmi ki o lé TẸJÚ MỌ́ ẹwà Olúwa
àti láti máa ṣe ÌWÁDÌÍ nínú tẹmpíli Rẹ̀.'
(Láti wo gbogbo ẹ̀kọ́ yìí, jọ̀wọ́ ṣe àbẹwò sí ojú òpó wẹ́ẹ̀bù wá, www.harvestchurch.org.au/onething)
Ní ọ̀sẹ̀ tió kọjá, a ti wo ohun tió túnmọ̀ sí láti wá OHÚN kan ṣoṣo náà. À n gbe nínú ayé tí kò jẹ ki á pa ọkàn pọ̀, èyí tí ó da orí ru, ayé aláriwo. Ní kókó o ṣe pàtàkì láti lè ṣé àdojukọ sí OHÚN kan péré. Nkán kán tí pàtàkì rẹ ju ohún gbogbo mìíràn tó bẹ́ẹ̀, o wa di nkán pàtó ti a tori rẹ̀ ṣe wà láàyè.
OHÚN kan yìí sì ni ìbátan wa pẹlú Jésù Krísti.
A sì ti wo àwọn kọ́kọ́rọ́ 5 tí a fi nwá OHÚN kan yí:
- ṢE BÉÈRÈ
- ṢE ÀWÁRÍ
- GBÉ INÚ
- WÒÓ
- ṢE ÌWÁDÌÍ
Ẹ̀ jẹ́ kí n gbà yín níyànjú bí a ṣe n mú ifọkansin yi wá sí òpin. Fí ẹ́sẹ̀ ìwé-mímọ́ yi ṣe ígbé ọkàn rẹ. Kàa ní ọ̀pọlọpọ àwọn ẹyà. Ṣe ìrántí rẹ. Sọ ọ́ nígbagbogbo.
Nítorí wípé ìgbésí ayé rẹ yíò yípadà nípasẹ ádùrá yìí.
'OHÚN kan li èmi ntọrọ ni ọdọ̀ Olúwa,
òun náà ni èmi yiò má WÁKIRI:
kí èmi ki o lé máa GBÉ INÚ ilé Olúwa
ní ọjọ ayé mí gbogbo,
kí èmi ki o lé MÁA WO ẹwà Olúwa
àti láti máa ṣe ÌWÁDÌÍ nínú tẹmpíli Rẹ̀.'
(Láti wo gbogbo ẹ̀kọ́ yìí, jọ̀wọ́ ṣe àbẹwò sí ojú òpó wẹ́ẹ̀bù wá, www.harvestchurch.org.au/onething)
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

A máa ri ohun tí ó túnmọ̀ sí láti gbé fún Jésù nínú ayé tí kò ní àfojúsùn. Ayé yìí n sáré, a sì ní ìròyìn ní àtẹ́lẹwọ́ wa ju bí a ṣe nílo lọ. Njẹ́ ìwà ayé tuntun yìí rèé? Báwo ni a ṣe lè rìn jẹ́jẹ́ ní ayé tí ó ń sáré yìí? Sáàmù 27:4 ní ìdáhùn – OHÙN KAN, pẹ̀lú Ps Andrew Cartledge.
More