Sekariah 9:16
Sekariah 9:16 YCB
OLúWA Ọlọ́run wọn yóò sì gbà wọ́n là ni ọjọ́ náà bí agbo ènìyàn rẹ̀: nítorí wọn ó dàbí àwọn òkúta adé, tí a gbé sókè bí ààmì lórí ilẹ̀ rẹ̀.