Mika 6:8

Mika 6:8 YCB

Ó ti fihàn ọ́, ìwọ ènìyàn, ohun tí ó dára, àti ohun tí OLúWA ń béèrè lọ́wọ́ rẹ? Bí kò ṣe láti ṣe òtítọ́, kí o sì fẹ́ràn àánú, àti kí o rìn ní ìrẹ̀lẹ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run rẹ̀.