Jona 2:2

Jona 2:2 YCB

Ó sì wí pé: “Nínú ìpọ́njú mi ni mo kígbe sí OLúWA, òun sì gbọ́ ohùn mi. Mo kígbe láti inú ipò òkú, mo pè fún ìrànwọ́, ìwọ sì gbọ́ ohùn mi.