Habakuku 2:14

Habakuku 2:14 YCB

Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ògo OLúWA, bí omi ti bo Òkun.