Amosi 5:15

Amosi 5:15 YCB

Kórìíra búburú kí o sì fẹ́ rere dúró ní orí òtítọ́ ní ilé ẹjọ́ bóyá OLúWA Ọlọ́run alágbára yóò ṣíjú àánú wo ọmọ Josẹfu tó ṣẹ́kù.