1
Sefaniah 3:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
OLúWA Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ, Ó ní agbára láti gbà ọ là. Yóò yọ̀ ni orí rẹ fún ayọ̀; Yóò tún ọ ṣe nínú ìfẹ́ rẹ̀, Yóò sì fi orin yọ̀ ní orí rẹ.”
ប្រៀបធៀប
រុករក Sefaniah 3:17
2
Sefaniah 3:20
Ní àkókò náà ni èmi yóò ṣà yín jọ; Nígbà náà ni èmi yóò mú un yín padà wá sílé. Èmi yóò fi ọlá àti ìyìn fún un yín láàrín gbogbo ènìyàn àgbáyé, nígbà tí èmi yóò yí ìgbèkùn yín padà bọ sípò ní ojú ara yín,” ni OLúWA wí.
រុករក Sefaniah 3:20
3
Sefaniah 3:15
OLúWA ti mú ìdájọ́ rẹ wọ̀n-ọn-nì kúrò, ó sì ti ti àwọn ọ̀tá rẹ padà sẹ́yìn. OLúWA, ọba Israẹli wà pẹ̀lú rẹ, Ìwọ kì yóò sì bẹ̀rù ibi kan mọ́.
រុករក Sefaniah 3:15
4
Sefaniah 3:19
Ní àkókò náà ni èmi yóò dojúkọ àwọn tí ń ni yín lára, èmi yóò gba àtiro là, èmi yóò sì ṣa àwọn tí ó ti fọ́nká jọ, èmi yóò fi ìyìn àti ọlá fún wọn ní gbogbo ilẹ̀ tí a bá ti dójútì wọ́n.
រុករក Sefaniah 3:19
គេហ៍
ព្រះគម្ពីរ
គម្រោងអាន
វីដេអូ