1
Sekariah 1:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
Nítorí náà sọ fún àwọn ènìyàn: Èyí ni ohun tí OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí: ‘Ẹ padà sí Ọ̀dọ̀ mi,’ Báyìí ní OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí, ‘èmi náà yóò sì padà sí ọ̀dọ̀ yín,’ ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí.
ប្រៀបធៀប
រុករក Sekariah 1:3
2
Sekariah 1:17
“Máa ké síbẹ̀ pé: Báyìí ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí: ‘A o máa fi ìre kún ìlú ńlá mi síbẹ̀; OLúWA yóò sì máa tu Sioni nínú síbẹ̀, yóò sì yan Jerusalẹmu síbẹ̀.’ ”
រុករក Sekariah 1:17
គេហ៍
ព្រះគម្ពីរ
គម្រោងអាន
វីដេអូ