ឡូហ្គូ YouVersion
ព្រះគម្ពីរគម្រោងអានវីដេអូ
ទាញយកកម្មវិធី
ជម្រើសភាសា
អាយខន ស្វែង​រក

ខគម្ពីរពេញនិយមពី Ọbadiah 1

1

Ọbadiah 1:17

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

Ṣùgbọ́n ìgbàlà yóò wà lórí òkè Sioni Wọn yóò sì jẹ́ mímọ́ àti ilé Jakọbu yóò sì ní ìní wọn

ប្រៀបធៀប

រុករក Ọbadiah 1:17

2

Ọbadiah 1:15

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

“Nítorí ọjọ́ OLúWA súnmọ́ etílé lórí gbogbo àwọn kèfèrí. Bí ìwọ ti ṣe, bẹ́ẹ̀ ni a ó ṣe sí ìwọ náà; ẹ̀san rẹ yóò sì yípadà sí orí ara rẹ.

ប្រៀបធៀប

រុករក Ọbadiah 1:15

3

Ọbadiah 1:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

Ìgbéraga àyà rẹ ti tàn ọ́ jẹ, ìwọ tí ń gbé inú pálapàla àpáta, tí o sì kọ́ ibùgbé rẹ sí ibi gíga, ìwọ wí nínú ọkàn rẹ pé, ‘ta ni yóò mú mi sọ̀kalẹ̀?’

ប្រៀបធៀប

រុករក Ọbadiah 1:3

4

Ọbadiah 1:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

Bí ìwọ tilẹ̀ gbé ara rẹ ga bí ẹyẹ idì, bí ìwọ tilẹ̀ tẹ́ ìtẹ́ rẹ sí àárín àwọn ìràwọ̀, láti ibẹ̀ ni èmi yóò ti sọ̀ ọ kalẹ̀,” ni OLúWA wí.

ប្រៀបធៀប

រុករក Ọbadiah 1:4

ជំពូកមុន
ជំពូកបន្ទាប់
YouVersion

ទទួលការលើកទឹកចិត្តនិងជំរុញឱ្យអ្នកស្វែងរកភាពស្និទ្ធស្នាលជាមួយនឹងព្រះជាម្ចាស់ជាប្រចាំថ្ងៃ។

ព័ន្ធកិច្ច

អំពី

អាជីព

អ្នកស្ម័គ្រចិត្ត

ប្លុកសារ

ដំណឹង

តំណមានប្រយោជន៍

ជំនួយ

បរិច្ចាគ

ជំនាន់​ព្រះ​គម្ពីរ

ព្រះគម្ពីរជាសំឡេង

ភាសា​ព្រះ​គម្ពីរ

ខគម្ពីរ​សម្រាប់​ថ្ងៃ​នេះ


ព័ន្ធកិច្ចបែបឌីជីថលរបស់

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

គោលការណ៍ច្បាប់ឯកជនលក្ខខណ្ឌ
កម្មវិធីបង្ហាញពីភាពងាយរងគ្រោះ
ហ្វេសប៊ុកTwitterអ៊ីនស្ដាក្រាមយូធូបPinterest

គេហ៍

ព្រះគម្ពីរ

គម្រោងអាន

វីដេអូ