1
Nahumu 3:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
Ègbé ni fún ìlú ẹ̀jẹ̀ nì, gbogbo rẹ̀ kún fún èké, ó kún fún olè, ìjẹ kò kúrò!
ប្រៀបធៀប
រុករក Nahumu 3:1
2
Nahumu 3:19
Kò sì sí ohun tí ó lè wo ọgbẹ́ ẹ̀ rẹ sàn; ọgbẹ́ rẹ kún fún ìrora Gbogbo ẹni tí ó bá sì gbọ́ ìròyìn rẹ yóò pàtẹ́wọ́ lé ọ lórí, nítorí ta ni kò ní pín nínú ìwà búburú rẹ ti kò ti lópin.
រុករក Nahumu 3:19
3
Nahumu 3:7
Gbogbo àwọn tí ó ba sì wò ọ́ yóò sì káàánú fún ọ, wọn yóò sì wí pé, ‘Ninefe ṣòfò: Ta ni yóò kẹ́dùn rẹ?’ Níbo ni èmi o ti wá olùtùnú fún ọ?”
រុករក Nahumu 3:7
គេហ៍
ព្រះគម្ពីរ
គម្រោងអាន
វីដេអូ