YouVersion Logo
Search Icon

ÌWÉ ÒWE 3:5-6

ÌWÉ ÒWE 3:5-6 YCE

Fi tọkàntọkàn gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, má sì tẹ̀lé ìmọ̀ ara rẹ. Mọ Ọlọrun ní gbogbo ọ̀nà rẹ, yóo sì mú kí ọ̀nà rẹ tọ́.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌWÉ ÒWE 3:5-6