YouVersion Logo
Search Icon

TẸSALONIKA KEJI 3:3-5

TẸSALONIKA KEJI 3:3-5 YCE

Ṣugbọn olódodo ni Oluwa, òun ni yóo fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀, tí yóo sì pa yín mọ́ kúrò ninu ibi gbogbo. A ní ìdánilójú ninu Oluwa nípa yín pé àwọn ohun tí a ti sọ, tí ẹ sì ń ṣe, ni ẹ óo máa ṣe. Oluwa yóo tọ́ ọkàn yín láti mọ ìfẹ́ Ọlọrun ati ohun tí Kristi faradà nítorí yín.

Video for TẸSALONIKA KEJI 3:3-5

Free Reading Plans and Devotionals related to TẸSALONIKA KEJI 3:3-5