Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 28 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

Mesaya ti wà níbí!
Kíni ìtumò ọ kí a fi ayé wa kalẹ fún àwọn ẹlòmíràn.

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Iye àìgbọràn Adamu àti ere ìgbọràn Jésù
Romu 5: 18-19

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ẹsẹ àti ipá rẹ̀ ní àbájáde ìparun. A dupẹ lọwọ Ọlọrun tí ọ ṣe ọnà tí ìràpadà nípa ore ọfẹ, nípasẹ iṣẹ́ tí Kristi ṣe

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Iwọ orísun gbogbo ìbùkún"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 27Ọjọ́ 29

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org